CAC Hymnal
CAC Hymn 815: Asegun ati Ajogun ni a je
1 f Asegun ati ajogun ni a je,Nipa eje Kristi a ni isegun;B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu;Ko s’ohun to le bori agbara Re. f Asegun ni wa, nipa eje Jesu;Baba fun wa ni