CAC Hymn 815: Asegun ati Ajogun ni a je

1 f Asegun ati ajogun ni a je,Nipa eje Kristi a ni isegun;B’Oluwa je tiwa, a ki yo subu;Ko s’ohun to le bori agbara Re. f Asegun ni wa, nipa eje Jesu;Baba fun wa ni ‘segun, nipa eje Jesu;Eni t’apa feleseSibe, O wa, O njoba;ff Awa ju asegun lo,Awa ju asegun lo. 2 f A […]